ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Sámúẹ́lì 23:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Lẹ́yìn náà, Sọ́ọ̀lù àti àwọn ọkùnrin rẹ̀ wá a wá.+ Nígbà tí wọ́n sọ fún Dáfídì, ní kíá, ó lọ sí ibi àpáta,+ ó sì dúró sí aginjù Máónì. Nígbà tí Sọ́ọ̀lù gbọ́, ó lépa Dáfídì wọ inú aginjù Máónì.

  • 1 Sámúẹ́lì 25:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ọkùnrin kan wà ní Máónì+ tó ń ṣiṣẹ́ ní Kámẹ́lì.*+ Ọkùnrin náà ní ọrọ̀ gan-an; ó ní ẹgbẹ̀rún mẹ́ta (3,000) àgùntàn àti ẹgbẹ̀rún kan (1,000) ewúrẹ́, ó sì ń rẹ́ irun àgùntàn rẹ̀ ní Kámẹ́lì. 3 Orúkọ ọkùnrin náà ni Nábálì,+ ìyàwó rẹ̀ sì ń jẹ́ Ábígẹ́lì.+ Ìyàwó yìí ní òye, ó sì rẹwà, ṣùgbọ́n ọkọ rẹ̀ tó jẹ́ ọmọ Kélẹ́bù+ le, ìwà rẹ̀ sì burú.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́