-
Diutarónómì 17:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “Tí o bá dé ilẹ̀ tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ fẹ́ fún ọ, tí o gbà á, tí o ti ń gbé ibẹ̀, tí o wá sọ pé, ‘Jẹ́ kí n yan ọba lé ara mi lórí, bíi ti àwọn orílẹ̀-èdè tó yí mi ká,’+
-
-
1 Sámúẹ́lì 8:7Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
7 Jèhófà sì sọ fún Sámúẹ́lì pé: “Fetí sí gbogbo ohun tí àwọn èèyàn náà sọ fún ọ; nítorí kì í ṣe ìwọ ni wọ́n kọ̀, èmi ni wọ́n kọ̀ ní ọba wọn.+
-