ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jóṣúà 19:47, 48
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Àmọ́ ilẹ̀ Dánì ti kéré jù fún wọn.+ Torí náà, wọ́n lọ bá Léṣémù + jà, wọ́n gbà á, wọ́n sì fi idà ṣá wọn balẹ̀. Ó di tiwọn, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í gbé ibẹ̀, wọ́n wá yí orúkọ Léṣémù pa dà sí Dánì, ìyẹn Dánì tó jẹ́ orúkọ baba ńlá wọn.+ 48 Èyí ni ogún ẹ̀yà Dánì ní ìdílé-ìdílé. Èyí sì ni àwọn ìlú náà pẹ̀lú àwọn ìgbèríko wọn.

  • Àwọn Onídàájọ́ 18:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Bákan náà, wọ́n sọ ìlú náà ní Dánì,+ ìyẹn Dánì orúkọ bàbá wọn, ẹni tí wọ́n bí fún Ísírẹ́lì.+ Àmọ́ Láíṣì ni ìlú náà ń jẹ́ tẹ́lẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́