-
1 Sámúẹ́lì 18:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Láti ọjọ́ yẹn lọ, ìgbà gbogbo ni Sọ́ọ̀lù ń wo Dáfídì tìfuratìfura.
-
-
Òwe 27:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Ìrunú jẹ́ ìwà ìkà, ìbínú sì dà bí àkúnya omi,
Àmọ́ ta ló lè dúró níwájú owú?+
-