2 Sámúẹ́lì 3:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Sọ́ọ̀lù ní wáhàrì* kan tó ń jẹ́ Rísípà,+ ọmọ Áyà. Lẹ́yìn náà, Íṣí-bóṣétì + sọ fún Ábínérì pé: “Kí ló dé tí o fi bá wáhàrì bàbá mi lò pọ̀?”+
7 Sọ́ọ̀lù ní wáhàrì* kan tó ń jẹ́ Rísípà,+ ọmọ Áyà. Lẹ́yìn náà, Íṣí-bóṣétì + sọ fún Ábínérì pé: “Kí ló dé tí o fi bá wáhàrì bàbá mi lò pọ̀?”+