-
2 Àwọn Ọba 17:24Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
24 Lẹ́yìn náà, ọba Ásíríà kó àwọn èèyàn wá láti Bábílónì, Kútà, Áfà, Hámátì àti Séfáfáímù,+ ó sì ní kí wọ́n máa gbé inú àwọn ìlú Samáríà níbi tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ń gbé tẹ́lẹ̀; wọ́n gba Samáríà, wọ́n sì ń gbé inú àwọn ìlú rẹ̀.
-