1 Sámúẹ́lì 1:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 1 Ọkùnrin kan wà, ó wá láti ìlú Ramataimu-sófíímù*+ ní agbègbè olókè Éfúrémù,+ orúkọ rẹ̀ ni Ẹlikénà,+ ọmọ Jéróhámù, ọmọ Élíhù, ọmọ Tóhù, ọmọ Súfì, ó jẹ́ ará Éfúrémù.
1 Ọkùnrin kan wà, ó wá láti ìlú Ramataimu-sófíímù*+ ní agbègbè olókè Éfúrémù,+ orúkọ rẹ̀ ni Ẹlikénà,+ ọmọ Jéróhámù, ọmọ Élíhù, ọmọ Tóhù, ọmọ Súfì, ó jẹ́ ará Éfúrémù.