-
Jẹ́nẹ́sísì 28:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 torí náà, Ísọ̀ lọ sọ́dọ̀ Íṣímáẹ́lì ọmọ Ábúráhámù, ó sì fẹ́ Máhálátì ọmọ Íṣímáẹ́lì tó jẹ́ arábìnrin Nébáótì. Ó fẹ́ ẹ kún àwọn ìyàwó tó ti ní.+
-