2 Kíróníkà 15:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Inú gbogbo Júdà dùn sí ìbúra náà, nítorí pé gbogbo ọkàn wọn ni wọ́n fi búra àti pé wọ́n fi ìtara wá a, ó sì jẹ́ kí wọ́n rí òun.+ Jèhófà sì ń fún wọn ní ìsinmi ní ibi gbogbo.+ Òwe 16:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Tí inú Jèhófà bá dùn sí ọ̀nà èèyàn,Ó máa ń mú kí àwọn ọ̀tá rẹ̀ pàápàá wà ní àlàáfíà pẹ̀lú rẹ̀.+
15 Inú gbogbo Júdà dùn sí ìbúra náà, nítorí pé gbogbo ọkàn wọn ni wọ́n fi búra àti pé wọ́n fi ìtara wá a, ó sì jẹ́ kí wọ́n rí òun.+ Jèhófà sì ń fún wọn ní ìsinmi ní ibi gbogbo.+