-
Àìsáyà 65:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
Èéfín ni àwọn yìí nínú ihò imú mi, iná tó ń jó láti àárọ̀ ṣúlẹ̀.
-
-
1 Jòhánù 1:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Tí a bá sọ pé, “A ò ní ẹ̀ṣẹ̀,” à ń tan ara wa,+ òótọ́ ò sì sí nínú wa.
-