Diutarónómì 32:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+ 1 Sámúẹ́lì 2:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 Jèhófà ń pani, ó sì ń dá ẹ̀mí ẹni sí;*Ó múni sọ̀ kalẹ̀ lọ sínú Isà Òkú,* ó sì ń gbéni dìde.+
39 Ẹ rí i báyìí pé èmi, àní èmi ni ẹni náà,+Kò sí ọlọ́run kankan yàtọ̀ sí mi.+ Mo lè pani, mo sì lè sọni di alààyè.+ Mo lè dá ọgbẹ́+ síni lára, mo sì lè woni sàn,+Kò sí ẹnì kankan tó lè gbani sílẹ̀ lọ́wọ́ mi.+