ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 79:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Wọ́n ti fi òkú àwọn ìránṣẹ́ rẹ ṣe oúnjẹ fún àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run,

      Wọ́n sì ti fi ẹran ara àwọn ẹni ìdúróṣinṣin rẹ fún àwọn ẹran inú igbó.+

       3 Wọ́n ti da ẹ̀jẹ̀ wọn sílẹ̀ bí omi káàkiri Jerúsálẹ́mù,

      Kò sì sí ẹni tó ṣẹ́ kù tó máa sin wọ́n.+

  • Ìsíkíẹ́lì 23:25
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 25 Èmi yóò bínú sí ọ, wọ́n á sì fi ìrunú bá ọ jà. Wọ́n á gé imú rẹ àti etí rẹ, idà ló sì máa pa àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú rẹ. Wọn yóò kó àwọn ọmọ rẹ ọkùnrin àti ọmọ rẹ obìnrin lọ, iná sì máa run àwọn tó bá ṣẹ́ kù nínú rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́