2 Kíróníkà 36:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Nítorí náà, ó gbé ọba àwọn ará Kálídíà+ dìde sí wọn, ẹni tó fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn+ nínú ibi mímọ́ wọn;+ kò ṣàánú ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin,* arúgbó tàbí aláàárẹ̀.+ Ohun gbogbo ni Ọlọ́run fi lé e lọ́wọ́.+ Jeremáyà 6:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+
17 Nítorí náà, ó gbé ọba àwọn ará Kálídíà+ dìde sí wọn, ẹni tó fi idà pa àwọn ọ̀dọ́kùnrin wọn+ nínú ibi mímọ́ wọn;+ kò ṣàánú ọ̀dọ́kùnrin tàbí ọ̀dọ́bìnrin,* arúgbó tàbí aláàárẹ̀.+ Ohun gbogbo ni Ọlọ́run fi lé e lọ́wọ́.+
11 Torí náà, ìbínú Jèhófà ti kún inú mi,Ara mi ò sì gbà á mọ́.”+ “Dà á sórí ọmọ tó wà lójú ọ̀nà,+Sórí àwọn àwùjọ ọ̀dọ́kùnrin tó kóra jọ. Gbogbo wọn ni ọwọ́ máa tẹ̀, láìyọ ọkùnrin kan àti ìyàwó rẹ̀ sílẹ̀,Àwọn àgbàlagbà pẹ̀lú àwọn arúgbó.*+