-
Dáníẹ́lì 4:12Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
12 Àwọn ewé rẹ̀ rẹwà, èso rẹ̀ pọ̀ yanturu, oúnjẹ sì wà lórí rẹ̀ fún gbogbo ayé. Àwọn ẹranko orí ilẹ̀ ń wá ibòji wá sábẹ́ rẹ̀, àwọn ẹyẹ ojú ọ̀run ń gbé lórí àwọn ẹ̀ka rẹ̀, gbogbo ohun alààyè* sì ń rí oúnjẹ jẹ lára rẹ̀.
-