-
Ìsíkíẹ́lì 39:28Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
28 “‘Wọ́n á wá mọ̀ pé èmi ni Jèhófà Ọlọ́run wọn nígbà tí mo bá mú kí wọ́n lọ sí ìgbèkùn ní àárín àwọn orílẹ̀-èdè, tí mo sì kó wọn jọ pa dà sórí ilẹ̀ wọn, láìfi ìkankan nínú wọn sílẹ̀.+
-
-
Sefanáyà 3:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ní àkókò yẹn, màá mú yín wọlé,
Ní àkókò tí mo kó yín jọ.
-