ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb19 April ojú ìwé 3
  • April 8-14

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • April 8-14
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2019
mwb19 April ojú ìwé 3

April 8-14

1 KỌ́RÍŃTÌ 10-13

  • Orin 30 àti Àdúrà

  • Ọ̀rọ̀ Ìbẹ̀rẹ̀ (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀)

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

  • “Jèhófà Jẹ́ Olóòótọ́”: (10 min.)

    • 1Kọ 10:13​—Jèhófà kọ́ ló ń fa àwọn àdánwò tó ń dé bá wa (w17.02 29-30)

    • 1Kọ 10:13​—Irú àwọn àdánwò tó “máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwọn èèyàn” ló máa ń ṣẹlẹ̀ sí àwa náà

    • 1Kọ 10:13​—Tá a bá gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, ó máa ràn wá lọ́wọ́ ká lè fara da àdánwò yòówù kó dé bá wa

  • Máa Walẹ̀ Jìn Nínú Ọ̀rọ̀ Ọlọ́run: (8 min.)

    • 1Kọ 10:8​—Kí nìdí tí ẹsẹ yìí fi sọ pé ẹgbẹ̀rún mẹ́tàlélógún (23,000) nínú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ló kú lọ́jọ́ kan ṣoṣo nígbà tí Nọ́ńbà 25:9 sọ pé ọ̀kẹ́ kan ó lé ẹgbàajì (24,000) ni? (w04 4/1 29)

    • 1Kọ 11:​5, 6, 10​—Ǹjẹ́ ó yẹ kí arábìnrin kan borí rẹ̀ tó bá ń darí ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì níbi tí arákùnrin wà? (w15 2/15 30)

    • Kí ni Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí kọ́ ẹ nípa Jèhófà?

    • Àwọn ìṣúra tẹ̀mí wo lo tún rí látinú Bíbélì kíkà ọ̀sẹ̀ yìí?

  • Bíbélì Kíkà: (4 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) 1Kọ 10:​1-17 (th ẹ̀kọ́ 5)

MÁA LO ARA RẸ LẸ́NU IṢẸ́ ÌWÀÁSÙ

  • Nígbà Àkọ́kọ́​—Fídíò: (4 min.) Ẹ wo fídíò náà, kẹ́ ẹ sì jíròrò rẹ̀.

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (2 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. (th ẹ̀kọ́ 1)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Onílé sọ ohun táwọn èèyàn sábà máa ń sọ ní ìpínlẹ̀ yín tí wọn kò bá fẹ́ gbọ́ ìwàásù. Fèsì ní ṣókí, kó o sì máa bá ọ̀rọ̀ rẹ lọ. (th ẹ̀kọ́ 3)

  • Nígbà Àkọ́kọ́: (3 min. tàbí kó máà tó bẹ́ẹ̀) Lo ohun tá a lè bá àwọn èèyàn sọ tó wà lójú ìwé 1. Fi ọ̀kan lára ìtẹ̀jáde tó wà nínú Àpótí Ìkọ́nilẹ́kọ̀ọ́ hàn án. (th ẹ̀kọ́ 6)

MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI

  • Orin 25

  • ‘Gbogbo Àwọn Ẹ̀yà Ara Jẹ́ Kò-Ṣeé-Má-Nìí’ (1Kọ 12:22): (10 min.) Jẹ́ kí àwọn ará wo fídíò náà.

  • “Báwo Lo Ṣe Lè Múra Sílẹ̀ fún Ìrántí Ikú Kristi?”: (5 min.) Àsọyé. Rọ àwọn ará pé kí wọ́n fi àsìkò Ìrántí Ikú Kristi ronú lórí ìfẹ́ tí Jèhófà àti Jésù ní sí wa, kí wọ́n sì túbọ̀ mọyì ìfẹ́ tí àwọn méjèèjì ní sí wa.

  • Ìkẹ́kọ̀ọ́ Bíbélì Ìjọ: (30 min.) bh orí 4 ¶15-22

  • Àtúnyẹ̀wò àti Ohun Tá A Máa Kọ́ Lọ́sẹ̀ Tó Ń Bọ̀ (3 min.)

  • Orin 31 àti Àdúrà

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́