April Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé April 2018 Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ April 2-8 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 26 Ìyàtọ̀ àti Ìjọra Tó Wà Láàárín Ìrékọjá àti Ìrántí Ikú Kristi April 9-15 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁTÍÙ 27-28 Ẹ Lọ Sọ Àwọn Ènìyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn—Kí Nìdí, Níbo àti Báwo? MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Iṣẹ́ Ìwàásù àti Kíkọ́ni Ṣe Pàtàkì Láti Sọ Àwọn Èèyàn Di Ọmọ Ẹ̀yìn April 16-22 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 1-2 “A Dárí Àwọn Ẹ̀ṣẹ̀ Rẹ Jì” April 23-29 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 3-4 Jésù Ṣe Ìwòsàn ní Ọjọ́ Sábáàtì April 30–May 6 ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN | MÁÀKÙ 5-6 Jésù Ní Agbára Láti Jí Àwọn Èèyàn Wa Tó Kú Dìde MÁA HÙWÀ TÓ YẸ KRISTẸNI Máa Lo Àwọn Ohun Tá A Fi Ń Kọ́ni Lẹ́kọ̀ọ́ Lọ́nà Tó Já Fáfá