-
Jẹ́nẹ́sísì 39:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 Nígbà tó yá, ó fi gbogbo ohun tó ní sí ìkáwọ́ Jósẹ́fù, kò sì da ara rẹ̀ láàmú nípa ohunkóhun àfi oúnjẹ tó ń jẹ. Yàtọ̀ síyẹn, Jósẹ́fù taagun, ó sì rẹwà.
-