Jẹ́nẹ́sísì 40:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Wọ́n fèsì pé: “Kálukú wa lá àlá, àmọ́ kò sẹ́ni tó máa túmọ̀ rẹ̀ fún wa.” Jósẹ́fù sọ fún wọn pé: “Ṣebí Ọlọ́run+ ló ni ìtúmọ̀? Ẹ jọ̀ọ́, ẹ rọ́ àlá yín fún mi.”
8 Wọ́n fèsì pé: “Kálukú wa lá àlá, àmọ́ kò sẹ́ni tó máa túmọ̀ rẹ̀ fún wa.” Jósẹ́fù sọ fún wọn pé: “Ṣebí Ọlọ́run+ ló ni ìtúmọ̀? Ẹ jọ̀ọ́, ẹ rọ́ àlá yín fún mi.”