-
Jẹ́nẹ́sísì 41:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Màlúù méje tó dára náà dúró fún ọdún méje. Bẹ́ẹ̀ náà ni àwọn ṣírí ọkà méje tó dára dúró fún ọdún méje. Ọ̀kan náà ni àwọn àlá náà, ohun kan náà ni wọ́n sì túmọ̀ sí.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 41:47Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
47 Ní ọdún méje tí ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ fi wà, ilẹ̀ náà méso jáde wọ̀ǹtìwọnti.*
-