-
Jẹ́nẹ́sísì 45:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Èmi yóò máa fún ọ ní oúnjẹ níbẹ̀, torí ó ṣì ku ọdún márùn-ún tí ìyàn+ á fi mú. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, ìwọ àti ilé rẹ máa di aláìní àti gbogbo ohun tí o ní.”’
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 47:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ṣé ó yẹ kí àwa àti ilẹ̀ wa kú níṣojú rẹ ni? Ra àwa àti ilẹ̀ wa, kí o fi fún wa lóúnjẹ, àwa yóò di ẹrú Fáráò, ilẹ̀ wa yóò sì di tirẹ̀. Fún wa ní irúgbìn ká lè wà láàyè, ká má bàa kú, kí ilẹ̀ wa má sì di ahoro.”
-