Jẹ́nẹ́sísì 46:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ásénátì+ ọmọ Pọ́tíférà àlùfáà Ónì* bí Mánásè+ àti Éfúrémù+ fún Jósẹ́fù ní ilẹ̀ Íjíbítì.