Ìṣe 7:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Àmọ́ Jékọ́bù gbọ́ pé oúnjẹ* wà ní Íjíbítì, ó sì rán àwọn baba ńlá wa jáde ní ìgbà àkọ́kọ́.+