-
Jẹ́nẹ́sísì 47:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jósẹ́fù sì ń gba gbogbo owó tó wà nílẹ̀ Íjíbítì àti Kénáánì tí àwọn èèyàn fi ra+ ọkà, Jósẹ́fù sì ń kó owó náà wá sínú ilé Fáráò.
-