-
Jẹ́nẹ́sísì 43:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Jósẹ́fù sáré jáde, torí ọkàn rẹ̀ fà sí àbúrò rẹ̀ débi pé kò lè mú un mọ́ra mọ́, ó sì wá ibì kan láti sunkún. Ó wọnú yàrá àdáni kan, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí í sunkún níbẹ̀.+
-