-
Jẹ́nẹ́sísì 42:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Tí ẹ bá jẹ́ olódodo, ẹ jẹ́ kí ọ̀kan nínú àwọn arákùnrin yín wà ní àtìmọ́lé níbí, àmọ́ kí ẹ̀yin tó kù máa lọ, kí ẹ sì gbé ọkà dání kí agbo ilé+ yín lè rí nǹkan jẹ.
-