-
Jẹ́nẹ́sísì 42:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 Ẹ rán ọ̀kan nínú yín kó lọ mú àbúrò yín wá, àmọ́ ẹ̀yin máa wà nínú ẹ̀wọ̀n níbí. Ohun tí màá fi mọ̀ nìyẹn bóyá òótọ́ lẹ̀ ń sọ. Àìjẹ́ bẹ́ẹ̀, bí Fáráò ti wà láàyè, amí ni yín.”
-