-
Jẹ́nẹ́sísì 42:25Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
25 Jósẹ́fù wá pàṣẹ pé kí wọ́n fi ọkà kún àwọn àpò wọn, kí wọ́n dá owó kálukú pa dà sínú àpò rẹ̀, kí wọ́n sì fún wọn ní oúnjẹ tí wọ́n á jẹ lójú ọ̀nà. Wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀ fún wọn.
-
-
Jẹ́nẹ́sísì 42:35Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
35 Bí wọ́n ṣe ń kó ẹrù inú àpò wọn jáde, àpò owó kálukú wà nínú rẹ̀. Nígbà tí àwọn àti bàbá wọn rí àpò owó wọn, ẹ̀rù bà wọ́n.
-