Jẹ́nẹ́sísì 42:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Ni wọ́n bá sọ pé: “Ọkùnrin méjìlá (12) ni àwa ìránṣẹ́ rẹ.+ Ọmọ bàbá kan+ náà ni wá, ilẹ̀ Kénáánì sì ni bàbá+ wa wà. Àbúrò wa tó kéré jù wà lọ́dọ̀ bàbá wa, àmọ́ àbúrò wa kejì ò sí mọ́.”+
13 Ni wọ́n bá sọ pé: “Ọkùnrin méjìlá (12) ni àwa ìránṣẹ́ rẹ.+ Ọmọ bàbá kan+ náà ni wá, ilẹ̀ Kénáánì sì ni bàbá+ wa wà. Àbúrò wa tó kéré jù wà lọ́dọ̀ bàbá wa, àmọ́ àbúrò wa kejì ò sí mọ́.”+