-
Jẹ́nẹ́sísì 43:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Àmọ́ tí o ò bá jẹ́ kó bá wa lọ, a ò ní lọ, torí ọkùnrin náà sọ fún wa pé, ‘Ẹ ò gbọ́dọ̀ tún fojú kàn mí mọ́ àfi tí ẹ bá mú àbúrò yín dání.’”+
-