ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 46:33, 34
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Tí Fáráò bá pè yín, tó sì bi yín pé, ‘Iṣẹ́ wo lẹ̀ ń ṣe?’ 34 Kí ẹ sọ pé, ‘Àti kékeré ni àwa ìránṣẹ́ rẹ ti ń tọ́jú ẹran ọ̀sìn, àwa àti àwọn baba ńlá+ wa,’ kí ẹ lè máa gbé ilẹ̀ Góṣénì,+ torí àwọn ará Íjíbítì+ kórìíra gbogbo àwọn tó ń da àgùntàn.”

  • Jẹ́nẹ́sísì 47:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Jósẹ́fù wá lọ sọ fún Fáráò+ pé: “Bàbá mi àti àwọn arákùnrin mi, agbo ẹran wọn, ọ̀wọ́ ẹran wọn àti gbogbo ohun ìní wọn ti dé láti ilẹ̀ Kénáánì, wọ́n sì ti wà ní ilẹ̀ Góṣénì.”+

  • Ẹ́kísódù 8:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Ní ọjọ́ yẹn, ó dájú pé màá ya ilẹ̀ Góṣénì sọ́tọ̀, níbi tí àwọn èèyàn mi ń gbé. Eṣinṣin mùjẹ̀mùjẹ̀ kankan ò ní sí níbẹ̀;+ èyí á sì jẹ́ kí o mọ̀ pé èmi Jèhófà wà ní ilẹ̀ yìí.+

  • Ẹ́kísódù 9:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Ilẹ̀ Góṣénì tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì wà nìkan ni yìnyín náà ò dé.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́