-
Jẹ́nẹ́sísì 43:34Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
34 Ó sì ń bù lára oúnjẹ tó wà lórí tábìlì rẹ̀ fún wọn, àmọ́ ìlọ́po márùn-ún èyí tó bù fún àwọn yòókù+ ló ń bù fún Bẹ́ńjámínì. Wọ́n wá ń jẹun pẹ̀lú rẹ̀, wọ́n sì ń mu títí wọ́n fi jẹun yó.
-