Jẹ́nẹ́sísì 32:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Lẹ́yìn ìyẹn, ó sọ pé: “Jẹ́ kí n máa lọ, torí ilẹ̀ ti ń mọ́.” Àmọ́ ó fèsì pé: “Mi ò ní jẹ́ kí o lọ, àfi tí o bá súre fún mi.”+
26 Lẹ́yìn ìyẹn, ó sọ pé: “Jẹ́ kí n máa lọ, torí ilẹ̀ ti ń mọ́.” Àmọ́ ó fèsì pé: “Mi ò ní jẹ́ kí o lọ, àfi tí o bá súre fún mi.”+