Jẹ́nẹ́sísì 35:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Nígbà kan tí Ísírẹ́lì ń gbé ilẹ̀ yẹn, Rúbẹ́nì lọ bá Bílíhà tó jẹ́ wáhàrì* bàbá rẹ̀ sùn, Ísírẹ́lì sì gbọ́ nípa rẹ̀.+ Àwọn ọmọkùnrin Jékọ́bù jẹ́ méjìlá (12).
22 Nígbà kan tí Ísírẹ́lì ń gbé ilẹ̀ yẹn, Rúbẹ́nì lọ bá Bílíhà tó jẹ́ wáhàrì* bàbá rẹ̀ sùn, Ísírẹ́lì sì gbọ́ nípa rẹ̀.+ Àwọn ọmọkùnrin Jékọ́bù jẹ́ méjìlá (12).