Nọ́ńbà 10:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Júdà ló kọ́kọ́ gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù sì ni olórí àwùjọ náà. 2 Sámúẹ́lì 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Nítorí náà, gbogbo àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ ọba ní Hébúrónì, Ọba Dáfídì sì bá wọn dá májẹ̀mú+ ní Hébúrónì níwájú Jèhófà. Lẹ́yìn náà, wọ́n fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì.+
14 Ẹ̀yà mẹ́ta ti ibùdó àwọn ọmọ Júdà ló kọ́kọ́ gbéra ní àwùjọ-àwùjọ,* Náṣónì+ ọmọ Ámínádábù sì ni olórí àwùjọ náà.
3 Nítorí náà, gbogbo àwọn àgbààgbà Ísírẹ́lì wá sọ́dọ̀ ọba ní Hébúrónì, Ọba Dáfídì sì bá wọn dá májẹ̀mú+ ní Hébúrónì níwájú Jèhófà. Lẹ́yìn náà, wọ́n fòróró yan Dáfídì ṣe ọba lórí Ísírẹ́lì.+