Jẹ́nẹ́sísì 48:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Lẹ́yìn náà, Ísírẹ́lì sọ fún Jósẹ́fù pé: “Wò ó, mi ò ní pẹ́ kú,+ àmọ́ ó dájú pé Ọlọ́run ò ní fi yín sílẹ̀, yóò sì mú yín pa dà sí ilẹ̀ àwọn baba ńlá+ yín.
21 Lẹ́yìn náà, Ísírẹ́lì sọ fún Jósẹ́fù pé: “Wò ó, mi ò ní pẹ́ kú,+ àmọ́ ó dájú pé Ọlọ́run ò ní fi yín sílẹ̀, yóò sì mú yín pa dà sí ilẹ̀ àwọn baba ńlá+ yín.