Jẹ́nẹ́sísì 46:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Èmi fúnra mi yóò bá ọ lọ sí Íjíbítì, èmi fúnra mi yóò sì mú ọ pa dà wá láti ibẹ̀,+ Jósẹ́fù yóò sì gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ.”*+ Jẹ́nẹ́sísì 47:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Nígbà tí àkókò tí Ísírẹ́lì máa kú+ sún mọ́ tòsí, ó pe Jósẹ́fù ọmọ rẹ̀, ó sì sọ pé: “Tí mo bá rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ fi ọwọ́ rẹ sábẹ́ itan mi, kí o fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi, kí o sì jẹ́ olóòótọ́ sí mi. Jọ̀ọ́, má sin mí sí Íjíbítì.+
4 Èmi fúnra mi yóò bá ọ lọ sí Íjíbítì, èmi fúnra mi yóò sì mú ọ pa dà wá láti ibẹ̀,+ Jósẹ́fù yóò sì gbé ọwọ́ rẹ̀ lé ojú rẹ.”*+
29 Nígbà tí àkókò tí Ísírẹ́lì máa kú+ sún mọ́ tòsí, ó pe Jósẹ́fù ọmọ rẹ̀, ó sì sọ pé: “Tí mo bá rí ojúure rẹ, jọ̀ọ́ fi ọwọ́ rẹ sábẹ́ itan mi, kí o fi ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ hàn sí mi, kí o sì jẹ́ olóòótọ́ sí mi. Jọ̀ọ́, má sin mí sí Íjíbítì.+