-
Jẹ́nẹ́sísì 41:43Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
43 Ó tún mú kí ó gun kẹ̀kẹ́ ẹṣin rẹ̀ kejì tó lọ́lá, ó sì ní kí wọ́n máa kígbe níwájú rẹ̀ pé, “Áfírékì!”* Bó ṣe fi Jósẹ́fù ṣe olórí gbogbo ilẹ̀ Íjíbítì nìyẹn.
-