Ẹ́kísódù 4:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Èyí mú kí àwọn èèyàn náà gbà á gbọ́.+ Nígbà tí wọ́n gbọ́ pé Jèhófà ti yíjú sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn,+ wọ́n tẹrí ba, wọ́n sì wólẹ̀.
31 Èyí mú kí àwọn èèyàn náà gbà á gbọ́.+ Nígbà tí wọ́n gbọ́ pé Jèhófà ti yíjú sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì+ àti pé ó ti rí ìyà tó ń jẹ àwọn,+ wọ́n tẹrí ba, wọ́n sì wólẹ̀.