Jẹ́nẹ́sísì 8:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Nóà sì mọ pẹpẹ+ kan fún Jèhófà, ó mú lára gbogbo ẹran tó mọ́ àti lára gbogbo ẹ̀dá tó ń fò+ tó sì mọ́, ó sì rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ náà.+
20 Nóà sì mọ pẹpẹ+ kan fún Jèhófà, ó mú lára gbogbo ẹran tó mọ́ àti lára gbogbo ẹ̀dá tó ń fò+ tó sì mọ́, ó sì rú ẹbọ sísun lórí pẹpẹ náà.+