-
Jẹ́nẹ́sísì 7:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Wọ́n wọlé, pẹ̀lú gbogbo ẹran inú igbó ní irú tiwọn, gbogbo ẹran ọ̀sìn ní irú tiwọn, gbogbo ẹran tó ń rákò ní ayé ní irú tiwọn, gbogbo ẹ̀dá tó ń fò ní irú tiwọn, títí kan gbogbo ẹyẹ àti gbogbo ẹ̀dá abìyẹ́. 15 Wọ́n ń wọlé lọ bá Nóà nínú áàkì, ní méjì-méjì, lára onírúurú ẹran tó ní ẹ̀mí.*
-