-
Jẹ́nẹ́sísì 1:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Torí náà, Ọlọ́run súre fún wọn pé: “Ẹ máa bímọ, kí ẹ sì pọ̀, kí ẹ kún inú omi òkun,+ kí àwọn ẹ̀dá tó ń fò sì pọ̀ ní ayé.”