ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 6:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Torí náà, Jèhófà sọ pé: “Èmi yóò run àwọn èèyàn tí mo ti dá kúrò lórí ilẹ̀, èèyàn àti ẹran ọ̀sìn, ẹran tó ń rákò àti àwọn ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, torí ó dùn mí pé mo dá wọn.”

  • Jẹ́nẹ́sísì 6:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 “Ní tèmi, màá mú kí ìkún omi  + bo ayé kí n lè run gbogbo ẹran ara tó ní ẹ̀mí* lábẹ́ ọ̀run. Gbogbo ohun tó wà ní ayé ló máa pa run.+

  • Jẹ́nẹ́sísì 9:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Àní, mo fìdí májẹ̀mú tí mo bá yín dá múlẹ̀: Ìkún omi ò tún ní pa gbogbo ẹran ara* run mọ́, ìkún omi ò sì ní pa ayé run mọ́.”+

  • Àìsáyà 54:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 “Bí àwọn ọjọ́ Nóà ló ṣe rí sí mi.+

      Bí mo ṣe búra pé omi Nóà ò ní bo ayé mọ́,+

      Bẹ́ẹ̀ náà ni mo búra pé mi ò ní bínú sí ọ mọ́, mi ò sì ní bá ọ wí mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́