Sáàmù 120:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo gbé, nítorí mo jẹ́ àjèjì ní Méṣékì!+ Mò ń gbé láàárín àwọn àgọ́ Kídárì.+ Ìsíkíẹ́lì 32:26 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 “‘Ibẹ̀ ni Méṣékì àti Túbálì+ àti gbogbo èèyàn wọn* tó pọ̀ rẹpẹtẹ wà. Sàréè wọn* yí i ká. Aláìdádọ̀dọ́* ni gbogbo wọn, wọ́n fi idà gún wọn pa, torí wọ́n dẹ́rù bani ní ilẹ̀ alààyè.
26 “‘Ibẹ̀ ni Méṣékì àti Túbálì+ àti gbogbo èèyàn wọn* tó pọ̀ rẹpẹtẹ wà. Sàréè wọn* yí i ká. Aláìdádọ̀dọ́* ni gbogbo wọn, wọ́n fi idà gún wọn pa, torí wọ́n dẹ́rù bani ní ilẹ̀ alààyè.