Jẹ́nẹ́sísì 2:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Jèhófà Ọlọ́run dá gbogbo ẹranko látinú ilẹ̀ àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, ó sì mú wọn wá sọ́dọ̀ ọkùnrin náà láti wo orúkọ tó máa sọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn; orúkọ tí ọkùnrin náà bá sì sọ ohun alààyè* kọ̀ọ̀kan ni wọ́n ń jẹ́.+
19 Jèhófà Ọlọ́run dá gbogbo ẹranko látinú ilẹ̀ àti gbogbo ẹ̀dá tó ń fò lójú ọ̀run, ó sì mú wọn wá sọ́dọ̀ ọkùnrin náà láti wo orúkọ tó máa sọ ọ̀kọ̀ọ̀kan wọn; orúkọ tí ọkùnrin náà bá sì sọ ohun alààyè* kọ̀ọ̀kan ni wọ́n ń jẹ́.+