Ẹ́sírà 4:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 (Ó wá látọ̀dọ̀ Réhúmù olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àti Ṣímúṣáì akọ̀wé òfin àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn yòókù, àwọn adájọ́ àti àwọn gómìnà kéékèèké, àwọn akọ̀wé, àwọn èèyàn Érékì,+ àwọn ará Babilóníà, àwọn tó ń gbé ní Súsà,+ ìyẹn àwọn ọmọ Élámù+
9 (Ó wá látọ̀dọ̀ Réhúmù olórí àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba àti Ṣímúṣáì akọ̀wé òfin àti àwọn ẹlẹgbẹ́ wọn yòókù, àwọn adájọ́ àti àwọn gómìnà kéékèèké, àwọn akọ̀wé, àwọn èèyàn Érékì,+ àwọn ará Babilóníà, àwọn tó ń gbé ní Súsà,+ ìyẹn àwọn ọmọ Élámù+