-
Òwe 8:30Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
30 Nígbà náà, mo wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí àgbà òṣìṣẹ́.+
Èmi ni àrídunnú rẹ̀+ lójoojúmọ́;
Inú mi sì ń dùn níwájú rẹ̀ ní gbogbo ìgbà;+
-