Jẹ́nẹ́sísì 20:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Ábúráhámù wá ṣí ibùdó rẹ̀ kúrò níbẹ̀+ lọ sí ilẹ̀ Négébù, ó sì ń gbé láàárín Kádéṣì+ àti Ṣúrì.+ Nígbà tó ń gbé* ní Gérárì,+
20 Ábúráhámù wá ṣí ibùdó rẹ̀ kúrò níbẹ̀+ lọ sí ilẹ̀ Négébù, ó sì ń gbé láàárín Kádéṣì+ àti Ṣúrì.+ Nígbà tó ń gbé* ní Gérárì,+