1 Kọ́ríńtì 11:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Nítorí kò yẹ kí ọkùnrin borí, torí ó jẹ́ àwòrán+ àti ògo Ọlọ́run, àmọ́ obìnrin jẹ́ ògo ọkùnrin.