Jẹ́nẹ́sísì 11:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Ìtàn Ṣémù+ nìyí. Ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún ni Ṣémù nígbà tó bí Ápákíṣádì+ ní ọdún kejì lẹ́yìn Ìkún Omi.
10 Ìtàn Ṣémù+ nìyí. Ẹni ọgọ́rùn-ún (100) ọdún ni Ṣémù nígbà tó bí Ápákíṣádì+ ní ọdún kejì lẹ́yìn Ìkún Omi.